Ṣeyi Law: Ẹf’ori Ji Mi, Fun Ohun Ti Mo Sọ Nipa Ijọba Tinubu
Gbajugbaja alawada ọmọ ilẹ yii kan, Oluwaṣeyi Lawrence ti ọpọ mọ si Ṣeyi Law lo ti ja’de wa tọrọ...
Gbajugbaja alawada ọmọ ilẹ yii kan, Oluwaṣeyi Lawrence ti ọpọ mọ si Ṣeyi Law lo ti ja’de wa tọrọ...
Ọga agba ile-iṣẹ iwe iroyin alariya, Ovation Magazine to tun ti fi igbakan ri gbero lati jẹ aarẹ l’orilẹ-ede...
Irawọ agbabọọlu ọmọ orilẹ-ede Naijiria to n gba bọọlu jẹun ni ilẹ Gẹẹsi gẹgẹ bi atamatase l’ọwọ iwaju fun...
Dele Momodu to jẹ gbajumọ oniroyin, ilumọọka ati oloṣelu lo dabi ẹni pe o jabọ kuro l’ọwọ apọnle Davido...
Gbajugbaja olorin ọgbọn ati imisi, Ṣẹgun Akinlolu ti ọpọ mọ pẹlu orukọ elere rẹ, iyẹn Beautiful Nubia lo ti...
Irawọ ori ikanni TikTok kan ti ọpọ mọ si Papaya Ex lo ke gbajare pe awọn kan ninu ẹṣọ...
Wahala nla lo n l’ọwọ bayii l’ori bi bulọga kan l’ori ayelujara ṣe f’ẹsun kan gbajugbaja oṣere Nollywood nni,...
Awọn ohun ti Ọlaṣubomi Raheem Ọkọya to jẹ ọmọ bibi inu baba olowo Eko kan, Rasaq Ọkọya ti ọpọ...
Mo Duro K’owo De Kin To D’ẹnu Kọ Iyawo Mi – Dapson Ọkunrin kan to jẹ adari fọnran orin...
Gbajumọ kan l’aarin ilu ti orukọ rẹ n jẹ Tokẹ Makinwa lo ti ṣ’alaye idi ti ko fi san...