Jẹ́nlògbà-tèmi
Ṣe loootọ ni Wumi, iyawo Mohbad, ti loyun ni?
Ọrọ to n ja ranyin bii ina ọyẹ́, to n jó fofo bii ẹwiri alagbedẹ lasiko yii ni ti...
Ẹ ba mi dupẹ gidigidi lọwọ Mercy Aigbe atọkọ ẹ o – Adeniyi Johnson
Ọpọ awọn ololufẹ oṣere tiata mejeeji yii ni ọrọ naa ṣi n ya lẹnu, nitori pe inu okunkun ni...
Eyi lamọran Laide Bakare f’awọn ọmọge asiko
Pẹlu bi ọpọlọpọ awon ọlọmọge ati awọn obinrin ṣe n lakaka lati di ilumọ-ọn-ka ati irawọ nidii iṣẹ aje...
Aluwẹ di ẹni aadọrin ọdun, Tinubu ṣ’adura fun un
Inu idunnu ati idupẹ ni ọkan pataki ninu awọn gbajumọ oṣere tiata ilẹ wa, Alagba Sunday Ọmọbọlanle, ti ọpọ...
O ma ṣe o! Awọn oṣere tiata ṣedaro ọmọ Saidi Balogun to ku lojiji
Titi dasiko ta a wa yii ni ọrọ ibanikẹdun ati aro ṣi n rọ wọle sori ikanni gbajugbaja oṣere...
Akara: Ounjẹ abalaye, ipanu aladun, ajẹpọnnula
Yoruba bọ, wọn ni ‘waa gba akara, waa gba du-n-du, lọmọde fi n mọ oju eeyan daadaa’. Akara jẹ...
Funkẹ Akindele gba ọmọ Naijiria lamọran pataki lọjọ ọdun ominira
“Ẹloo, orukọ mi ni Funkẹ Akindele, ti inagijẹ rẹ n jẹ Jẹnifa. Oni ni ayajọ ajọdun ominira Naijiria. Naijiria...
Ẹniọla Badmus binu fesi fawọn to ni aye ẹ maa ri bii aye Naijiria
Yoruba bọ, wọn ni ‘isọrọ-nigbesi, isunmusi nigbete-gan-n-gan. Ọrọ yii lo wọ bi gbajugbaja oṣere-binrin onitiata ilẹ wa to lomi...
Ṣẹyin naa ti gbọ ohun ti Lateef Adedimeji ṣe fawọn ẹlẹgbẹ rẹ?
Lateef Adedimeji Ẹsẹ ko gba ero l’Ọjọruu, Wẹsidee, ọjọ kẹẹẹdọgbọn, oṣu Kẹsan-an, ọdun 2024 nile iworan sinima nla kan...