Ile-ẹjọ wọgi le ẹbẹ Wasiu Ayinde lori ọrọ Awujalẹ tuntun, amọ…
Watch Listen Live TV Latari bo ṣe wọ Gomina atawọn afọbajẹ re kootu, eyi laṣẹ ti Adajọ pa fun...
Watch Listen Live TV Latari bo ṣe wọ Gomina atawọn afọbajẹ re kootu, eyi laṣẹ ti Adajọ pa fun...
Gbajugbaja onifọnran alawada l’ori ayelujara (comedy skit maker) ati olorin takasufe, Nasboi lo ti fi ero rẹ han laipẹ...
Gẹgẹ bi ọkan pataki ninu awọn perete to jẹ gbajumọ ṣugbọn ti ọpọ mọ wọn fun dida ọwẹkẹ (chitchat)...
Ori lo ko gbajumọ ọdọmọkunrin l’ori ikanni TikTok, Peller yọ ninu ewu ijamba ọkọ ninu ọkọ Mercedes tuntun to...
Gbajugbaja olorin Fuji, Wasiu Ayinde Marshall ti awọn miiran n pe ni Kwam 1 n lo ti fi orin...
Gbajugbaja olokoowo orin (Music Executive) to tun jẹ apo-orin-pọ (Music Producer) ati olorin (Music Artiste) Michael Collins Ajerah ti...
Ọmọbinrin ọlọwọ ṣibi kan ti orukọ rẹ n jẹ Damilọla Adeparusi ti ọpọ mọ si Cheff Dammy ti okiki...
L’aarin awuyewuye nla to gb’ode kan l’ori ọrọ eekan olorin nni, Innocent Ujah Idibiah ti ọpọ mọ si 2Baba...