Wahala Bẹ Silẹ Ni South Africa, Wọn L’awọn o fẹ Ọba awon Igbo
Wahala nla lo bẹ silẹ lana ode yi ni’lu KuGompo to wa ni agbegbe ẹkun ilaoorun Cape ni orilẹ-ede...
Wahala nla lo bẹ silẹ lana ode yi ni’lu KuGompo to wa ni agbegbe ẹkun ilaoorun Cape ni orilẹ-ede...
Ẹgbẹ oselu All Progressives Congress (APC) ti gbe idajọ gbe’le ẹ alainigbedeke (indefinite suspension) kalẹ fun ẹni to jẹ...
Pẹlu omije l’oju ni oṣerebinrin nni, Damilọla Adekọya ti ọpọ mọ si Princess Comedian fi n bu epe jo...
Irawọ olorin takasufe olohun arinkinkin nni, Chike-Ezekpeazu Osebuka ti ọpọ mọ si Chike lo ti ni, laye, oun ko...
Minisita f’ọrọ ohun amusagbara, Adebayọ Adelabu ti tọrọ aforijin lọwọ awọn ọmọ orilẹ-ede Naijiria l’ori bi ina ọba ṣe...
Nṣe ni ọrọ di bo-o-lọ-o-ya-n-mi ni igboro ilu Abuja, nigba ti Tajudeen Baruwa ati ikọ rẹ gbakoso olu-ile ẹgbẹ...
Gbajugbaja oṣere tiata ati alawada, Lanre Omiyinka ti ọpọ mọ si Baba Ijẹṣa ni irawọ oṣere’binrin, Iyabọ Ojo ti...
Iṣẹlẹ kayefi gba lo wa’ye niluu kan ti wọn pe ni Ozoro, iyẹn ni ipinlẹ Delta. Ohun eemọ kan...
Gẹrẹ lẹyin ti ile-ẹjọ gba ki wọn o gba beeli Abubakar Malami ti ṣe Agbef’ọba Agba ati Alakoso tẹlẹ...
Igbimọ b’ọba-ṣe’lu ilu Benin ni ipinlẹ Edo lo ti bẹrẹ igbesẹ ibawi bayii fun olori kan l’aafin nitori ti...