Priscilla, ọmọ Iyabọ Ojo ti mu ọkọ wa’le
Priscilla, ọmọ gbajumọ oṣere-binrin ilẹ wa nni, Iyabọ Ojo, rẹwa o si gbafẹ lori ẹrọ ayelujara. Ọpọ awuyewuye lo...
Priscilla, ọmọ gbajumọ oṣere-binrin ilẹ wa nni, Iyabọ Ojo, rẹwa o si gbafẹ lori ẹrọ ayelujara. Ọpọ awuyewuye lo...
Idris Okunẹyẹ, ọmọkunrin alafẹ to maa n ṣe bii obinrin nni, Bobrisky sọ ohun t’oju rẹ ri l’ẹwọn Kirikiri...
Awọn to n gbero lati gba iwe-aṣẹ irinna siluu oyinbo gbọdọ gbaradi lati san owo igbawe-aṣẹ tuntun, latari bijọba...
Yoruba bọ wọn lọjọ iku laa dere, gbaju-gbaja onkọrin Juju nni, Sunday Iṣọla Adegẹye ti gbogbo eeyan mọ si...
Owe Yoruba to ni iku ti iba pa’ni, to ba ṣi ni fila, o t’ọpẹ, owe naa ti ṣẹ...
Bo tilẹ jẹ pe awọn mọlẹbi gbajugbaja ọdọmọde olorin hipọọpu to ku l’ọdun to kọja nni, Ilerioluwa Ọladimeji Alọba,...
Titi dasiko ta a fi n ko iroyin yii jọ lọwọ ni ojo ọrọ ibanikẹdun ati idaro ṣi n...
Ni bayii, ẹni moju ogun ni yoo bẹrẹ si i pabi n’Ire fun ikọ agbabọọlu agba ilẹ wa, Super...
Podcast Itafaaji TV E be wa wo lojoojumo fun ohun ti o dara ju nipa ti orin ibile ati...
Laipẹ yii ni gbaju-gbaja onkọrin taka-sufee (hippup) kan, Ọgbẹni David Adeleke, ti wọn n pe ni Davido, tabi OBO,...