Oge ṣiṣe ni ilẹ Yoruba
Owe kan nilẹ Yoruba sọ pe: Iku ogun ni i pa akikanju, iku odo ni i pa omuwẹ, iku...
Owe kan nilẹ Yoruba sọ pe: Iku ogun ni i pa akikanju, iku odo ni i pa omuwẹ, iku...
Ọkan ninu owe Yoruba to gbajumọ daadaa lọ bayii: Gele ko dun bii ka mọ ọn we, ka mọ...
Yoruba ko kẹrẹ to ba dọrọ imura, itunraṣe, oge ṣiṣe, ṣiṣe ẹwa lọṣọọ ati irisi. Ko le ma ri...
Yoruba bọ, wọn ni ẹni ti ko gbọ tẹnu ẹga ni yoo sọ pe ẹyẹ oko n pàátó. Irawọ...
Oṣere tiata to rẹwa, to si jafafa nidi iṣẹ rẹ ni Ẹniọla Badmus. Bi ọrọ ṣe da ṣaka lẹnu...
Latari bo ṣe fidi rẹmi niwaju Daniel Dubois, awọn eeyan kan ti n sọ pe Anthony Joshua ko ni...
Yoruba bọ, wọn ni bi ina ko ba tan laṣọ, ẹjẹ ko nii tan leekanna, bi ẹni a n...
Ilumọ-ọn-ka arẹwa oṣere tiata, obinrin bọrọkọtọ bii ọka nni, Bisọla Badmus, sọ iwa ti baba ọmọ rẹ, Wasiu Ayinde...
Ṣinkin bii ẹni jẹ tẹtẹ oriire ni inu awọn araalu kan lagbegbe Oke-Ọya ilẹ Naijiria n dun bayii, latari...
Ilumọ-ọn-ka onigbọwọ awọn abẹṣẹẹku-bi-ojo kan, Ọgbẹni Frank Warren ti sọ asọtẹlẹ nipa idije ẹṣẹ kikan to maa waye laipẹ...