Ṣẹyin naa ti gbọ ohun to ṣẹlẹ laaarin Nkechi Blessing ati Mista Latin ni Canada?
Titi di asiko yii ni igbesẹ akin ti ilumọ-ọn-ka oṣere tiata ilẹ wa to rẹwa daadaa nni, Abilekọ Nkechi...
Titi di asiko yii ni igbesẹ akin ti ilumọ-ọn-ka oṣere tiata ilẹ wa to rẹwa daadaa nni, Abilekọ Nkechi...
Ajanaku sun bii oke, erin ṣubu ko le dide, bẹẹ lakukọ kọ lẹyin ọmọkunrin. Ọfọ nla ti tun ṣẹlẹ...
Ni bayii, ajọ to n ṣakoso ere bọọlu alafẹsẹgba lágbayé, Fédération Internationale de Football Association, ti gbogbo eeyan mọ...
King Wasiu Ayinde, KWAM 1, lo d’aṣa ninu awo orin rẹ kan pe ‘ṣe o da a mọ too...
Ajọ CAF to n ṣakoso ere bọọlu alafẹsẹgba ni ilẹ Africa, iyẹn Confederation of African Football, ti gbe idajọ...
Bo ba jẹ awada lasan ni ọdọmọkunrin to ti fẹrẹ sọ ara ẹ di obinrin tan nni, Idris Ọlanrewaju...
Watch Listen Live TV Ṣe bi ko ba nidii, ẹṣẹ ki i deede ṣẹ, bi Yoruba ti n sọ,...
Maa jaye oni o, Mi o m’ẹyin ọla o, maa jaye oni o, mi o m’ẹyin ọla o Ẹsẹ...
Eyin ka, ile ẹrin wo, aferemojo ku, ẹnu isa n ṣọfọ! Ọrọ yii lo ṣe wẹku pẹlu bi awujọ...
Watch Listen Live TV Bi wọn ba beere ‘ọmọ ti wọn n sọ’, ọmọ to ta lẹnu lasiko yii,...