Oriṣiiriṣii ere idaraya lo kun ilẹ Yoruba pitimu. Oniruuru ọna la n gba daraya, titi kan awọn ere ìmárale ati ẹ̀fẹ̀. Laye ọjọ́un titi di oni, agbo ere idaraya n pọ si i, o si tubọ n gbajumọ si i.

Itafaaji

Eré Ìdárayá

Start typing and press Enter to search