Eguavoen di akọni-mọ-ọn-gba tuntun fun Super Eagles
Ni bayii, ẹni moju ogun ni yoo bẹrẹ si i pabi n’Ire fun ikọ agbabọọlu agba ilẹ wa, Super...
Oriṣiiriṣii ere idaraya lo kun ilẹ Yoruba pitimu. Oniruuru ọna la n gba daraya, titi kan awọn ere ìmárale ati ẹ̀fẹ̀. Laye ọjọ́un titi di oni, agbo ere idaraya n pọ si i, o si tubọ n gbajumọ si i.
Ni bayii, ẹni moju ogun ni yoo bẹrẹ si i pabi n’Ire fun ikọ agbabọọlu agba ilẹ wa, Super...