Eyi nidi ti mo ṣe fa ori mi kodoro – Yvonne Jẹgẹdẹ
King Wasiu Ayinde, KWAM 1, lo d’aṣa ninu awo orin rẹ kan pe ‘ṣe o da a mọ too...
Oge ṣiṣe jẹ ọkan pataki ninu aṣa ilẹ Yoruba, to kan imura, iwọṣọ, iṣaraloge, itunraṣe, ẹwa ati irisi awọn eeyan. Yoruba fọwọ pataki mu Oge ṣiṣe, oriṣiiriṣii ọna si ni wọn n gba ṣe e, lati ilu kan si omi-in.
King Wasiu Ayinde, KWAM 1, lo d’aṣa ninu awo orin rẹ kan pe ‘ṣe o da a mọ too...
Maa jaye oni o, Mi o m’ẹyin ọla o, maa jaye oni o, mi o m’ẹyin ọla o Ẹsẹ...
Pẹlu bi ọpọlọpọ awon ọlọmọge ati awọn obinrin ṣe n lakaka lati di ilumọ-ọn-ka ati irawọ nidii iṣẹ aje...
Owe kan nilẹ Yoruba sọ pe: Iku ogun ni i pa akikanju, iku odo ni i pa omuwẹ, iku...
Ọkan ninu owe Yoruba to gbajumọ daadaa lọ bayii: Gele ko dun bii ka mọ ọn we, ka mọ...
Yoruba ko kẹrẹ to ba dọrọ imura, itunraṣe, oge ṣiṣe, ṣiṣe ẹwa lọṣọọ ati irisi. Ko le ma ri...