Ṣẹyin naa ti gbọ ohun to ṣẹlẹ laaarin Nkechi Blessing ati Mista Latin ni Canada?
Titi di asiko yii ni igbesẹ akin ti ilumọ-ọn-ka oṣere tiata ilẹ wa to rẹwa daadaa nni, Abilekọ Nkechi...
Titi di asiko yii ni igbesẹ akin ti ilumọ-ọn-ka oṣere tiata ilẹ wa to rẹwa daadaa nni, Abilekọ Nkechi...
Ajanaku sun bii oke, erin ṣubu ko le dide, bẹẹ lakukọ kọ lẹyin ọmọkunrin. Ọfọ nla ti tun ṣẹlẹ...
King Wasiu Ayinde, KWAM 1, lo d’aṣa ninu awo orin rẹ kan pe ‘ṣe o da a mọ too...
Maa jaye oni o, Mi o m’ẹyin ọla o, maa jaye oni o, mi o m’ẹyin ọla o Ẹsẹ...
Eyin ka, ile ẹrin wo, aferemojo ku, ẹnu isa n ṣọfọ! Ọrọ yii lo ṣe wẹku pẹlu bi awujọ...
Watch Listen Live TV Bi wọn ba beere ‘ọmọ ti wọn n sọ’, ọmọ to ta lẹnu lasiko yii,...
Titi dasiko ta a wa yii ni ọrọ ibanikẹdun ati aro ṣi n rọ wọle sori ikanni gbajugbaja oṣere...
Yọmi Fabiyi, gbajumọ oṣere tiata ilẹ wa, to tun n ṣiṣẹ ajafẹtọọ-ọmọniyan, ti wọn tun n pe ni Araba...
“Ẹloo, orukọ mi ni Funkẹ Akindele, ti inagijẹ rẹ n jẹ Jẹnifa. Oni ni ayajọ ajọdun ominira Naijiria. Naijiria...