Erin wo! Baba Agbako ti ku o!
Ajanaku sun bii oke, erin ṣubu ko le dide, bẹẹ lakukọ kọ lẹyin ọmọkunrin. Ọfọ nla ti tun ṣẹlẹ...
Ajanaku sun bii oke, erin ṣubu ko le dide, bẹẹ lakukọ kọ lẹyin ọmọkunrin. Ọfọ nla ti tun ṣẹlẹ...
King Wasiu Ayinde, KWAM 1, lo d’aṣa ninu awo orin rẹ kan pe ‘ṣe o da a mọ too...
Ajọ CAF to n ṣakoso ere bọọlu alafẹsẹgba ni ilẹ Africa, iyẹn Confederation of African Football, ti gbe idajọ...
Maa jaye oni o, Mi o m’ẹyin ọla o, maa jaye oni o, mi o m’ẹyin ọla o Ẹsẹ...
Watch Listen Live TV Bi wọn ba beere ‘ọmọ ti wọn n sọ’, ọmọ to ta lẹnu lasiko yii,...
Tibi tire la da ile aye, b’awọn agba ṣe maa n sọ, ti wọn si maa n ṣadura pe...
Ọrọ to n ja ranyin bii ina ọyẹ́, to n jó fofo bii ẹwiri alagbedẹ lasiko yii ni ti...
Ọpọ awọn ololufẹ oṣere tiata mejeeji yii ni ọrọ naa ṣi n ya lẹnu, nitori pe inu okunkun ni...
Inu idunnu ati idupẹ ni ọkan pataki ninu awọn gbajumọ oṣere tiata ilẹ wa, Alagba Sunday Ọmọbọlanle, ti ọpọ...