Ori ko Portable olorin yọ lọwọ janduku l’Ekoo
Owe Yoruba to ni iku ti iba pa’ni, to ba ṣi ni fila, o t’ọpẹ, owe naa ti ṣẹ...
Owe Yoruba to ni iku ti iba pa’ni, to ba ṣi ni fila, o t’ọpẹ, owe naa ti ṣẹ...
Bo tilẹ jẹ pe awọn mọlẹbi gbajugbaja ọdọmọde olorin hipọọpu to ku l’ọdun to kọja nni, Ilerioluwa Ọladimeji Alọba,...
Titi dasiko ta a fi n ko iroyin yii jọ lọwọ ni ojo ọrọ ibanikẹdun ati idaro ṣi n...
Laipẹ yii ni gbaju-gbaja onkọrin taka-sufee (hippup) kan, Ọgbẹni David Adeleke, ti wọn n pe ni Davido, tabi OBO,...