lagos
Ile Mercy Aigbe to jona: Aṣiri nla foju hande
Oriṣiiriṣii ọrọ, ero, ifọrọwerọ ati isọrọsi lo ti n ja ranyin lori ẹrọ ayelujara bayii latari iṣẹlẹ ibanujẹ to...
Wọn l’orin ti Saheed Oṣupa ṣẹṣẹ kọ yii, orin ija ni o!
Watch Listen Live TV Awuyewuye tuntun to n lọ n’igboro ati lori ẹrọ ayelujara lasiko yii, agaga laaarin awọn...
Lẹyin Baba Agbako, gbajumọ oṣere tiata mi-in tun dagbere faye!
Watch Listen Live TV Leyii ti ko tii to ọsẹ kan ti eekan oṣere tiata ilẹ Yoruba ti wọn...
Bobrisky tun ti ha o! Bọ́dà Sẹmẹ lọwọ ti tẹ ẹ
Bo ba jẹ awada lasan ni ọdọmọkunrin to ti fẹrẹ sọ ara ẹ di obinrin tan nni, Idris Ọlanrewaju...
Priscilla, ọmọ Iyabọ Ojo ti mu ọkọ wa’le
Priscilla, ọmọ gbajumọ oṣere-binrin ilẹ wa nni, Iyabọ Ojo, rẹwa o si gbafẹ lori ẹrọ ayelujara. Ọpọ awuyewuye lo...
Bobrisky sọ tuntun: Mo fẹẹ pada si ẹwọn Kirikiri yẹn!
Idris Okunẹyẹ, ọmọkunrin alafẹ to maa n ṣe bii obinrin nni, Bobrisky sọ ohun t’oju rẹ ri l’ẹwọn Kirikiri...
Eyi laṣiiri to wa laaarin emi ati Onyeka Onwenu to ku – Sunny Ade
Yoruba bọ wọn lọjọ iku laa dere, gbaju-gbaja onkọrin Juju nni, Sunday Iṣọla Adegẹye ti gbogbo eeyan mọ si...
Ori ko Portable olorin yọ lọwọ janduku l’Ekoo
Owe Yoruba to ni iku ti iba pa’ni, to ba ṣi ni fila, o t’ọpẹ, owe naa ti ṣẹ...