marriage
Nitori Davido, awọn aye rọ̀’jò epe kàbìtì fun Pasitọ yii!
Watch Listen Live TV Owe Yoruba kan ni ‘ọmọ ọsàn ni i kó póḿpó ba iya rẹ, ati pe...
Nitori igbeyawo Priscilla, Iyabọ Ojo ko si pampẹ EFCC
Watch Listen Live TV Owe Yoruba kan ni bi ori ba ṣe tobi to lo ṣe n fọ olori,...
Igbeyawo mi to daru lo dun mi julọ laye mi – Mercy Aigbe
Watch Listen Live TV Ilumọ-ọn-ka arẹwa oṣere tiata to tun fẹran okoowo ṣiṣe nni, Mercy Aigbe ti ṣalaye pe...
Igbeyawo ọmọ Iyabọ Ojo de, imura yii pọ!
Watch Listen Live TV Priscilla and Juma Jux Priscilla and Juma Jux Bi ki i ba ṣe pe oge...
Eyi lohun to ṣẹlẹ lọjọ ti Iyabọ Ojo sin ọmọ rẹ re’le ọkọ
Watch Listen Live TV Iroyin idunu nla gbaa lo je ni’gba ti oro de’gboro wipe Priscilla omo Iyabo Ojo,...
Bimbọ Ademoye bu sẹkun lode ariya igbeyawo
Watch Listen Live TV Yoruba bọ, wọn ni ọrọ ṣe’ni wo, ka le m’ẹni to f’ẹni. Ọrọ yii lo...
Ijo ọpẹ lẹsẹ ree Ṣọla Ṣobọwale, ọmọ rẹ n re’le ọkọ
Watch Listen Live TV B’eeyan ba pade gbajumọ oṣere-binrin ilẹ wa nni, Ṣọla Ṣobọwale nibi to ti n f’ẹsẹ...
Eyi lamọran Laide Bakare f’awọn ọmọge asiko
Pẹlu bi ọpọlọpọ awon ọlọmọge ati awọn obinrin ṣe n lakaka lati di ilumọ-ọn-ka ati irawọ nidii iṣẹ aje...
Priscilla, ọmọ Iyabọ Ojo ti mu ọkọ wa’le
Priscilla, ọmọ gbajumọ oṣere-binrin ilẹ wa nni, Iyabọ Ojo, rẹwa o si gbafẹ lori ẹrọ ayelujara. Ọpọ awuyewuye lo...