Ẹniọla Badmus tọrọ aforiji lọwọ Ọmọborty, eyi lohun to ṣẹlẹ
Eniola Badmus Omoborty Bo tilẹ jẹ pe ko sẹni to fura pe nnkan kan to le di ija nla...
Eniola Badmus Omoborty Bo tilẹ jẹ pe ko sẹni to fura pe nnkan kan to le di ija nla...
Priscilla, ọmọ gbajumọ oṣere-binrin ilẹ wa nni, Iyabọ Ojo, rẹwa o si gbafẹ lori ẹrọ ayelujara. Ọpọ awuyewuye lo...
Idris Okunẹyẹ, ọmọkunrin alafẹ to maa n ṣe bii obinrin nni, Bobrisky sọ ohun t’oju rẹ ri l’ẹwọn Kirikiri...
Yoruba bọ wọn lọjọ iku laa dere, gbaju-gbaja onkọrin Juju nni, Sunday Iṣọla Adegẹye ti gbogbo eeyan mọ si...
Owe Yoruba to ni iku ti iba pa’ni, to ba ṣi ni fila, o t’ọpẹ, owe naa ti ṣẹ...
Bo tilẹ jẹ pe awọn mọlẹbi gbajugbaja ọdọmọde olorin hipọọpu to ku l’ọdun to kọja nni, Ilerioluwa Ọladimeji Alọba,...
Titi dasiko ta a fi n ko iroyin yii jọ lọwọ ni ojo ọrọ ibanikẹdun ati idaro ṣi n...
Ni bayii, ẹni moju ogun ni yoo bẹrẹ si i pabi n’Ire fun ikọ agbabọọlu agba ilẹ wa, Super...
Laipẹ yii ni gbaju-gbaja onkọrin taka-sufee (hippup) kan, Ọgbẹni David Adeleke, ti wọn n pe ni Davido, tabi OBO,...