Ṣẹyin naa ti gbọ ohun to ṣẹlẹ si Jide Kosọkọ?
Tibi tire la da ile aye, b’awọn agba ṣe maa n sọ, ti wọn si maa n ṣadura pe...
Tibi tire la da ile aye, b’awọn agba ṣe maa n sọ, ti wọn si maa n ṣadura pe...
Ọrọ to n ja ranyin bii ina ọyẹ́, to n jó fofo bii ẹwiri alagbedẹ lasiko yii ni ti...
Pẹlu bi ọpọlọpọ awon ọlọmọge ati awọn obinrin ṣe n lakaka lati di ilumọ-ọn-ka ati irawọ nidii iṣẹ aje...
Owe kan nilẹ Yoruba sọ pe: Iku ogun ni i pa akikanju, iku odo ni i pa omuwẹ, iku...
Yoruba ko kẹrẹ to ba dọrọ imura, itunraṣe, oge ṣiṣe, ṣiṣe ẹwa lọṣọọ ati irisi. Ko le ma ri...
Yoruba bọ, wọn ni ẹni ti ko gbọ tẹnu ẹga ni yoo sọ pe ẹyẹ oko n pàátó. Irawọ...
Oṣere tiata to rẹwa, to si jafafa nidi iṣẹ rẹ ni Ẹniọla Badmus. Bi ọrọ ṣe da ṣaka lẹnu...
Eniola Badmus Omoborty Bo tilẹ jẹ pe ko sẹni to fura pe nnkan kan to le di ija nla...
Priscilla, ọmọ gbajumọ oṣere-binrin ilẹ wa nni, Iyabọ Ojo, rẹwa o si gbafẹ lori ẹrọ ayelujara. Ọpọ awuyewuye lo...