Ọfọ Ṣẹ L’agbo’le Tiata, Agba-Ọjẹ Oṣere – Kola Oyewọ Ja’de L’aye
Gbajugbaja agbaojẹ oṣerekunrin elere ori itage ati ti sinima agbelewo, dokita Kọla Oyewọ to kopa ninu sinima Ṣaworoide lo...
Gbajugbaja agbaojẹ oṣerekunrin elere ori itage ati ti sinima agbelewo, dokita Kọla Oyewọ to kopa ninu sinima Ṣaworoide lo...
Gbajumọ ori ẹrọ ayelujara ti ọrọ rẹ maa n saba mu awuyewuye lọwọ, Mandy Ayomiposi ti ọpọ eeyan mọ...
Tẹle ipapoda gbajugbaja arẹwa oṣerekunrin Alex Ekubo, ẹni to dagbere f’aye lẹni ogoji (40) ọdun l’at’ari aisan jẹjẹrẹ, isin...
Gbajugbaja onkọrin takasufe, David Adeleke ti gbogbo eeyan mọ si Davido ṣe ayipada ere rẹ nibi ayẹyẹ imura 2026...
Gbajumọ afọrọlede ati aṣoju awọn ile-iṣẹ lori ẹrọ ayelujara, Okoro Blessing Nkiruka ti gbogbo eeyan mọ si Blessing CEO...
Gbajugbaja olorin ẹmi ti orin rẹ ma n mu agbara dani – Esther Igbẹkẹle, lo ti pa’riwo si’ta pe...
Adẹrinpoṣonu Bovi Ugboma ti ọpọ eeyan mọ si Bovi ti ni oun maa ṣatilẹyin fun igbeyawo to ba tuka...
Gbajugbaja olorin takasufe binrin Oyinkansola Sarah Aderibigbe ti gbogbo eeyan mọ si Ayra Starr lo ti fesi si ọrọ...
Agbefọnranjade l’ori ayelujara Habeeb Hamzat ti ọpọ eeyan mọ si Peller lo ti f’oruka s’ọwọ ọrẹbinrin ati agbefọnranjade l’ori...
Ilumọọka onkọrin fuji Remi Aluko ti sọrọ lori aisan to n ba ja leyi to ti fa ko ma...