EMI KII FẸNU-KO’NU NINU ERE, Ẹ BA MI WA IPA MIIRAN – TOYỌ BABY
Gbajugbaja arẹwa oṣere nni, Julianah Ọlayọde ti ọpọ mọ si Tọyọ Baby lati inu sinima olokiki kan – Jennifer’s...
Gbajugbaja arẹwa oṣere nni, Julianah Ọlayọde ti ọpọ mọ si Tọyọ Baby lati inu sinima olokiki kan – Jennifer’s...
Ogbontarigi irawọ oṣere ati agbe sinima ja’de, Kunle Afọlayan lo ti ja’de wa s’ọrọ nipa ere rẹ tuntun “Anikulapo...
Ogbontarigi irawọ oṣere nni, Fathia Balogun ni iya rẹ, Mama Talayo Abẹni Tẹniọla ku l’asiko ayẹyẹ ọjọ-ibi Fathia.Ayẹyẹ nla...
Gbajugbaja onkọrin Afrobeats, David Adeleke ti ọpọ mọ si Davido lo ti jẹ ko di mimọ pe oun ko...
Sinima tuntun “Oversabi Aunty” lat’ọwọ gbajugbaja oṣere nni, Toyin Aimakhu Abraham lo ti pa biliọnu kan naira ni sinima...
Bi ọtẹ to gbona janjan l’aarin Ṣeun Kuti ati Wizkid ṣe n tẹ siwaju ni ọrọ naa n ka...
Gbajugbaja onkorin takasufe kan, to tun ti tẹwọ gba ami ẹyẹ Grammy ti orukọ rẹ n jẹ Ne-Yo lo...
Lẹyin ti Aanu iyẹn ọmọ ti Ayọ Labinjoh ni oun bi fun Davido beere pe ki Davido o wa...
Yatọ fun jijẹ olokiki nidi iṣẹ orin ati amuludun, David Adeleke ti ọpọ tun mọ si Davido lo tun...
Òǹkà láti 1 – 200 English Yoruba 1 (one) 1 (Ookan/ení) 2 – (Two) 2 – méjì 3 –...