Rotimi Salami: Mi O Le Kọ’mọ Koda Ki Ayẹwo DNA N Emi Kọ Ni Baba Rẹ
Gbajugbaja oṣere Nollywood nni, Rotimi Salami ti fi iha to kọ si ọrọ ṣiṣe iwadii lati mọ ojulowo baba...
Gbajugbaja oṣere Nollywood nni, Rotimi Salami ti fi iha to kọ si ọrọ ṣiṣe iwadii lati mọ ojulowo baba...
Agbabọọlu ọmọ orilẹ-ede Naijiria kan, Daniel Daga ni ile-ẹjọ kan l’orilẹ-ede Norway ti da’jọ ewọn fun bayii l’ori jij’ẹbi...
Ọkan pataki ninu awọn agbẹnusọ fun Aarẹ Orilẹ-ede Naijiria, Aṣiwaju Bọla Tinubu ti orukọ rẹ n jẹ Daniel Bwala...
Ọga agba ile-iṣẹ iwe iroyin alariya, Ovation Magazine to tun ti fi igbakan ri gbero lati jẹ aarẹ l’orilẹ-ede...
Dele Momodu to jẹ gbajumọ oniroyin, ilumọọka ati oloṣelu lo dabi ẹni pe o jabọ kuro l’ọwọ apọnle Davido...
Gbajugbaja olorin ọgbọn ati imisi, Ṣẹgun Akinlolu ti ọpọ mọ pẹlu orukọ elere rẹ, iyẹn Beautiful Nubia lo ti...
Irawọ ori ikanni TikTok kan ti ọpọ mọ si Papaya Ex lo ke gbajare pe awọn kan ninu ẹṣọ...
Pasitọ iyẹn Oluṣọ Aguntan ile ijọsin kan l’eko, David Christian Centre ti orukọ rẹ n jẹ Pasitọ Kingsley Okonkwo...
Ko jẹ tuntun mọ pe ọrẹminu pataki ni Rotimi Salami jẹ si irawọ oṣere ati adari ere, Allwell Ademọla...
Ogbontarigi irawọ oṣere ati agbe sinima ja’de, Kunle Afọlayan lo ti ja’de wa s’ọrọ nipa ere rẹ tuntun “Anikulapo...