Aṣofin Temi Yatọ Bi Mo Ba Di Sinetọ L’Abuja – Aisha Yesufu
Gbajugbaja ajafẹtọ, Aisha Yesufu lo ti sọ pe igba ti ẹ yo yatọ bi oun ba le wọle gẹgẹ...
Gbajugbaja ajafẹtọ, Aisha Yesufu lo ti sọ pe igba ti ẹ yo yatọ bi oun ba le wọle gẹgẹ...
Gomina tẹlẹri nipinlẹ Anambra to tun jẹ adije dupo aarẹ labẹ asia ẹgbẹ oṣelu NDC, Peter Obi ti fẹnu...
Aarẹ-Ọna Kakanfo ilẹ Yoruba, Oloye Iba Gani Adams lo ti kọminu lori ipo ti eto aabo wa nilẹ yii,...
Lẹyin iṣẹlẹ ijinigbe to waye si awọn akẹẹkọ ati olukọ ni ijọba ibilẹ Oriire ni agbegbe Ogbomoso ni ipinlẹ...
Gomina ipinlẹ Kano, Alhaji Abba Kabir Yusuf ti ọpọ mọ si Abba Gida Gida lo ti sọ oko ọrọ...
Ilumọọka oṣerekunrin Emeka Ike ti fi erongba rẹ han lati dije dupo wọle aṣojuṣofin. Erongba yii lo fi lede...
Gbajugbaja arẹwa oṣerebinrin, Bukky Wright lo t’ẹnu bọ itan ti ọpọ awọn eniyan to fi mọ awọn ololufẹ rẹ...
Ajọ ajafẹtọ ọmọ-niyan Amnesty International ti ke gbajare lori ogunlọgọ awọn ọmọ ile-iwe ti wọn jigbe l’ẹkun ariwa ati...
Gbajumọ amuludun, Pascal Okechukwu “Cubana Chief Priest” to tun jẹ alakoso fun ẹgbẹ “City Boy Movement” ẹka ti ipinlẹ...
Lati nnkan ọjọ diẹ sẹyin ti iroyin jade pe gbajugbaja olorin olohun-arẹdodo, Chike ati Sandra to jẹ aya gbajumọ...