Baba Ijẹṣa, Yo Orukọ Awọn Ọmọ L’ẹnu Rẹ abi Ko R’ogun Ẹjọ L’ẹẹkan si – Iyabo Ojo
Gbajugbaja oṣere tiata ati alawada, Lanre Omiyinka ti ọpọ mọ si Baba Ijẹṣa ni irawọ oṣere’binrin, Iyabọ Ojo ti...
Gbajugbaja oṣere tiata ati alawada, Lanre Omiyinka ti ọpọ mọ si Baba Ijẹṣa ni irawọ oṣere’binrin, Iyabọ Ojo ti...
Iṣẹlẹ kayefi gba lo wa’ye niluu kan ti wọn pe ni Ozoro, iyẹn ni ipinlẹ Delta. Ohun eemọ kan...
Gẹrẹ lẹyin ti ile-ẹjọ gba ki wọn o gba beeli Abubakar Malami ti ṣe Agbef’ọba Agba ati Alakoso tẹlẹ...
Igbimọ b’ọba-ṣe’lu ilu Benin ni ipinlẹ Edo lo ti bẹrẹ igbesẹ ibawi bayii fun olori kan l’aafin nitori ti...
Gbajugbaja irawọ olorin ọmọ ilẹ wa nni, Ọlọlade Ahmed Aṣakẹ ti ọpọ mọ si Aṣakẹ abi Ọlọlade Mr Money...
N ṣe ni ọrọ di bo-o-lọ-o-ya-n-mi ni’gboro ilu Abuja, nigba ti Tajudeen Baruwa ati ikọ rẹ gbakoso olu-ile ẹgbẹ...
Gbajugbaja oṣere Nollywood nni, Rotimi Salami ti fi iha to kọ si ọrọ ṣiṣe iwadii lati mọ ojulowo baba...
Agbabọọlu ọmọ orilẹ-ede Naijiria kan, Daniel Daga ni ile-ẹjọ kan l’orilẹ-ede Norway ti da’jọ ewọn fun bayii l’ori jij’ẹbi...
Ọkan pataki ninu awọn alakoso (minisita) ninu ijọba Aarẹ Bọla Tinubu, ti tun ṣe alakoso f’ọrọ ina-ọba l’orilẹ-ede Naijiria,...
Ogbontarigi akọnimọọgba (coach) tẹlẹ fun ikọ ẹgbẹ agbabọọlu agba-ọjẹ ilẹ wa iyẹn Super Eagles to tun jẹ Agba-Oye Ọtun...