Wọn ti jawee ‘gbele ẹ’ fun rẹfiri to leri pe oun maa pa agbabọọlu yii o
Orin wo ni ka kọ si gbẹdu lọrọ di nigba ti esuro padida to n le aja laarin alakooso...
Oriṣiiriṣii ere idaraya lo kun ilẹ Yoruba pitimu. Oniruuru ọna la n gba daraya, titi kan awọn ere ìmárale ati ẹ̀fẹ̀. Laye ọjọ́un titi di oni, agbo ere idaraya n pọ si i, o si tubọ n gbajumọ si i.
Orin wo ni ka kọ si gbẹdu lọrọ di nigba ti esuro padida to n le aja laarin alakooso...
Lateef Adedimeji Ẹsẹ ko gba ero l’Ọjọruu, Wẹsidee, ọjọ kẹẹẹdọgbọn, oṣu Kẹsan-an, ọdun 2024 nile iworan sinima nla kan...
Latari bo ṣe fidi rẹmi niwaju Daniel Dubois, awọn eeyan kan ti n sọ pe Anthony Joshua ko ni...
Ilumọ-ọn-ka onigbọwọ awọn abẹṣẹẹku-bi-ojo kan, Ọgbẹni Frank Warren ti sọ asọtẹlẹ nipa idije ẹṣẹ kikan to maa waye laipẹ...
Ni bayii, ẹni moju ogun ni yoo bẹrẹ si i pabi n’Ire fun ikọ agbabọọlu agba ilẹ wa, Super...