UZOR ARUKWE ṢE’LERI ẸWỌN F’ẸNI TO L’OUN FUN BAMBAM, OṢERE AKẸGBẸ RẸ L’OYUN
Wahala nla lo n l’ọwọ bayii l’ori bi bulọga kan l’ori ayelujara ṣe f’ẹsun kan gbajugbaja oṣere Nollywood nni,...
Wahala nla lo n l’ọwọ bayii l’ori bi bulọga kan l’ori ayelujara ṣe f’ẹsun kan gbajugbaja oṣere Nollywood nni,...
Pasitọ iyẹn Oluṣọ Aguntan ile ijọsin kan l’eko, David Christian Centre ti orukọ rẹ n jẹ Pasitọ Kingsley Okonkwo...
Ko jẹ tuntun mọ pe ọrẹminu pataki ni Rotimi Salami jẹ si irawọ oṣere ati adari ere, Allwell Ademọla...
Ogbontarigi irawọ oṣere ati agbe sinima ja’de, Kunle Afọlayan lo ti ja’de wa s’ọrọ nipa ere rẹ tuntun “Anikulapo...
Ogbontarigi irawọ oṣere nni, Fathia Balogun ni iya rẹ, Mama Talayo Abẹni Tẹniọla ku l’asiko ayẹyẹ ọjọ-ibi Fathia.Ayẹyẹ nla...
Bi ọtẹ to gbona janjan l’aarin Ṣeun Kuti ati Wizkid ṣe n tẹ siwaju ni ọrọ naa n ka...
Gbajugbaja onkorin takasufe kan, to tun ti tẹwọ gba ami ẹyẹ Grammy ti orukọ rẹ n jẹ Ne-Yo lo...
Lẹyin ti Aanu iyẹn ọmọ ti Ayọ Labinjoh ni oun bi fun Davido beere pe ki Davido o wa...
Yatọ fun jijẹ olokiki nidi iṣẹ orin ati amuludun, David Adeleke ti ọpọ tun mọ si Davido lo tun...
Irawọ oṣere Nollywood kan to fi igba kan mu’le si oke okun, ni orilẹ-ede Amẹrika to ti wa pada...