O ma ṣe o! Ọjọgbọn Ade Ọjẹniyi ti jade laye!
Ọkan pataki ninu awọn agbatẹru ati igi lẹyin ọgbà ileeṣẹ Quantum Valley Limited to fikalẹ s’agbegbe Igbọkọda, nipinlẹ Ondo,...
Ọkan pataki ninu awọn agbatẹru ati igi lẹyin ọgbà ileeṣẹ Quantum Valley Limited to fikalẹ s’agbegbe Igbọkọda, nipinlẹ Ondo,...
Ọrọ to n ja ranyin bii ina ọyẹ́, to n jó fofo bii ẹwiri alagbedẹ lasiko yii ni ti...
Ọpọ awọn ololufẹ oṣere tiata mejeeji yii ni ọrọ naa ṣi n ya lẹnu, nitori pe inu okunkun ni...
Pẹlu bi ọpọlọpọ awon ọlọmọge ati awọn obinrin ṣe n lakaka lati di ilumọ-ọn-ka ati irawọ nidii iṣẹ aje...
Inu idunnu ati idupẹ ni ọkan pataki ninu awọn gbajumọ oṣere tiata ilẹ wa, Alagba Sunday Ọmọbọlanle, ti ọpọ...
Titi dasiko ta a wa yii ni ọrọ ibanikẹdun ati aro ṣi n rọ wọle sori ikanni gbajugbaja oṣere...
Yoruba bọ, wọn ni ‘waa gba akara, waa gba du-n-du, lọmọde fi n mọ oju eeyan daadaa’. Akara jẹ...
“Ẹloo, orukọ mi ni Funkẹ Akindele, ti inagijẹ rẹ n jẹ Jẹnifa. Oni ni ayajọ ajọdun ominira Naijiria. Naijiria...
Yoruba bọ, wọn ni ‘isọrọ-nigbesi, isunmusi nigbete-gan-n-gan. Ọrọ yii lo wọ bi gbajugbaja oṣere-binrin onitiata ilẹ wa to lomi...