Fìlà: Àlékún ẹwà ati oge awọn ọkunrin nilẹ Yoruba (Apa Kinni)
Yoruba ko kẹrẹ to ba dọrọ imura, itunraṣe, oge ṣiṣe, ṣiṣe ẹwa lọṣọọ ati irisi. Ko le ma ri...
Oge ṣiṣe jẹ ọkan pataki ninu aṣa ilẹ Yoruba, to kan imura, iwọṣọ, iṣaraloge, itunraṣe, ẹwa ati irisi awọn eeyan. Yoruba fọwọ pataki mu Oge ṣiṣe, oriṣiiriṣii ọna si ni wọn n gba ṣe e, lati ilu kan si omi-in.
Yoruba ko kẹrẹ to ba dọrọ imura, itunraṣe, oge ṣiṣe, ṣiṣe ẹwa lọṣọọ ati irisi. Ko le ma ri...