Ọdun kan Iku Mohbad: Yọmi Fabiyi atawọn ọdọ fẹẹ ṣewọde nla n’Ikorodu
Bo tilẹ jẹ pe awọn mọlẹbi gbajugbaja ọdọmọde olorin hipọọpu to ku l’ọdun to kọja nni, Ilerioluwa Ọladimeji Alọba,...
Bo tilẹ jẹ pe awọn mọlẹbi gbajugbaja ọdọmọde olorin hipọọpu to ku l’ọdun to kọja nni, Ilerioluwa Ọladimeji Alọba,...
Titi dasiko ta a fi n ko iroyin yii jọ lọwọ ni ojo ọrọ ibanikẹdun ati idaro ṣi n...
Laipẹ yii ni gbaju-gbaja onkọrin taka-sufee (hippup) kan, Ọgbẹni David Adeleke, ti wọn n pe ni Davido, tabi OBO,...