Celebrity
Ko si àbámọ̀ kankan nipa igbesi aye mi o – Obesere
Watch Listen Live TV Lọjọ iṣile ati ayẹyẹ ọjọọbi, Obesere sọrọ igbesi aye ẹ Gbajúgbajà onkọrin Fuji nni, Abass...
Idaamu Portable: “Mi o lọọ kọrin ni London mọ, adura ni mo nilo!”
Watch Listen Live TV Portable to maa n daṣa ‘wahala, wahala’ wọ wahala gidi lọdọ ijọba Asiko yii kii...
Fathia Balogun dẹni ọdun marundinlọgọta laye, eyi lọrọ to sọ!
Watch Listen Live TV Ọlọjọọbi tuntun, Fathia Williams Balogun, ko le pa ayọ rẹ mọra! Ilumọ-ọn-ka apọnbeporẹ oṣere-binrin onitiata...
“Ẹẹmẹta loyun bajẹ lara mi, lawọn dokita ba sọ pe…” – Dayọ Amusa
Watch Listen Live TV Dayọ Amusa ni ọkọ oun nigba yẹn ti le lọmọ ogoji ọdun, o dẹ loun...
Ẹkun abiyamọ! Iya Olori Naomi bu sẹkun gbaragada!
Watch Listen Live TV Iran to ṣeni laaanu gidigidi ni iran ọhun, iran to gbomi loju ẹni ni, ko...
Awọn eeyan nlanla ṣedaro Cash Madam to ku
Watch Listen Live TV Eekan olorin Juju nni, Oloye Ebenezer Obey, lo fun mama naa ni inagijẹ “Cash Madam”...
Imura Mercy Aigbe yii, wọn loo ta lẹnu lọjọọbi ẹ!
Watch Listen Live TV Bi wọn ba pe Mercy Aigbe, oṣere-binrin apọnbeporẹ to tun fẹran okoowo kara-kata ni ọmọ...