Ìròyìn Jẹ́nlògbà-tèmi Ẹ Sinmi Isọkusọ, Emi ati 2Face O Ti Pada O – Annie Idibia Tosin Ẹ Sinmi Isọkusọ, Emi ati 2Face O Ti Pada O - Annie Idibia Oṣerebinrin Annie Idibia ti ko iroyin to n tan ka pe oun ati ọkọ rẹ tẹlẹ, gbajugbaja onkọrin Tuface Idibia ti pada danu.O ko ọrọ naa danu lori itakun ibanidọrẹ Instagram rẹ nibi to ti n tọka pe awọn fọnran to n tan ka naa ti pẹ. O fi kun pe iroyin ofege lasan ni. Ahesọ ọrọ naa bẹrẹ ni ọjọ jimoh to kọja lẹyin ti fọnran kan to ti pẹ ṣafihan awọn ololufẹ tẹlẹri naa nibi ti wọn ti n fi ifẹ han si ara wọn ni kilọbu. Fọnran naa to tan ka lo fa ti ọpọ fi ro pe awọn mejeeji ti pada.Ti ẹ o ba gbagbe, Annie ati Tuface ti wọn jẹ ololufẹ ọjọ pipẹ ni igbeyawo wọn tuka lẹyin ọmọ meji ninu oṣu kini ọdun yii. Previous post O Ma Ṣe O, Iku Doro!Ẹgbọn Ọọni Ile-Ifẹ Jade Laye Next post Eyi Ni Bi Ọrọ Owo Ṣe Di’ja L’aarin Davido ati VDM Leave a Comment Cancel replyYour email address will not be published. Save my name, email, and website in this browser for the next time I comment. Δ You Might Also Like Aṣiri Tu! Igboho L’oun Mọ Awọn Ti Wọn Wa Nidi Ijinigbe L’Ọyọ June 4, 2026 Oṣelu B’oju Ọrẹ Gomina Seyi Makinde Ati Oriyomi Jẹ! Ẹ Wa Gbọ Ohun T’Oriyomi Sọ August 10, 2026 Eemọ, Ẹ Wa Wo Ilu ti Wọn Ti n Ṣ’ọdun Ifipa-ba-ni-lo-pọ Nipinlẹ Delta March 29, 2026