Asọtẹlẹ Nipa Tinubu ati Adelabu Lati Ẹnu Primate Ayọdele Lori Idibo Ọdun 2027
Gbajugbaja alufaa to gbajumọ fun sisọ asọtẹlẹ nipa oṣelu orilẹ-ede Naijiria, Primate Elijah Ayọdele ti sọ bi nnkan yo...
Gbajugbaja alufaa to gbajumọ fun sisọ asọtẹlẹ nipa oṣelu orilẹ-ede Naijiria, Primate Elijah Ayọdele ti sọ bi nnkan yo...
Agbo tiata ati ẹka amuludun lapapọ dawọọ idunnu bi ogbontarigi oṣerebinrin nni, Ṣọla Ṣobowale ṣe fi ọmọ rẹ, Olamide...
Adije dupo Aarẹ tẹlẹri labẹ asia ẹgbẹ Oṣelu Labour Party, Peter Obi ati Gomina tẹlẹri ni Ipinlẹ Kano, Rabiu...
Ilumọọka oṣere, Funkẹ Akindele ti ọpọ mọ si Jenifa jẹ ko di mimọ pe oun kii lọ si ile-ijọsin...
Mejila ninu awọn ọmọ ọrinlenigbadinmẹrin ti wọn jigbe ni ile-iwe girama Government Girls Secondary School to wa lagbegbe Chibok...
Ọmọ Gomina Ademọla Adeleke ti ipinlẹ Ọṣun, to tun jẹ gbajugbaja onkọrin, Adebayọ Adeleke to ọpọ mọ si B-Red...
Ile-ẹjọ to gaju lọ lorilẹede Naijira ti wọgi le apejọpọ Ẹgbẹ Oṣelu PDP to waye nilu Ibadan nipinlẹ Ọyọ...
Igbakeji Aarẹ tẹlẹ ri, Ọjọgbọn Yẹmi Ọṣinbajo lo ti ṣalaye idi to fi pa oti mimu ti, lẹyin aimọye...
Gbajugbaja Oṣere Tọkọtaya nni, Lateef Adedimeji ati Adebimpe Oyebade Adedimeji ni wọn ti dawọ idunnu lori bi wọn ṣe...
Aarẹ Bola Ahmed Tinubu ti yan Ọgbẹni Joseph Tegbe gẹgẹ bi Minisita fun oun Amuṣagbara nilẹ wa pẹlu bi...