AMVCA: Ṣọla Ṣobọwale, Kanayo Kanayo, Lateef Adedimeji ati Awọn Miiran Gba Ami-Ẹyẹ
Ẹsẹ ko gba ero ni gbọngan ayẹyẹ Eko Hotels l’aṣalẹ ana ti ayẹyẹ ami-ẹyẹ AMVCA ti waye nilu Eko....
Ẹsẹ ko gba ero ni gbọngan ayẹyẹ Eko Hotels l’aṣalẹ ana ti ayẹyẹ ami-ẹyẹ AMVCA ti waye nilu Eko....
Ilumọọka aṣoju awọn ile-iṣẹ to tun jẹ ọmọ gbajugbaja oṣere binrin Iyabo Ojo, Priscilla Ojo ti ṣaṣọ loju bii...
Awọn ọmọ Ikọ ologun ilẹ wa ti wọn n koju awọn agbesunmọmi ni ẹkun iwọ oorun ariwa ti wọn...
Seyi Vibez ati Adekunle Gold Awọn ọrọ buruku pau bi ibọn lo n bọọlẹ lati ẹnu gbajugbaja olorin takasufe...
Obi, Kwankwaso ati Seriakie Dickson ninu ipade apapo ẹgbẹ NDC Ẹgbẹ oṣelu Nigeria Democratic Congress (NDC) ti fi tikẹti...
Ẹgbẹ Agbabọọlu to gbayi l’agbaye nni, Barcelona FC ni wọn ti tọwọ bọ iwe adehun lati da ile-iwe ẹkọ...
Aarẹ tẹlẹ ri l’orilẹ-ede Naijiria, Ọmọwe Goodluck Jonathan ni awọn kan korajọ lọ ba ni ọfisi rẹ to wa...
Sultan tilu Sokoto, Sa’ad Abubakar kẹta ti sọ pe ẹnikẹni to ba pa eniyan ẹgbẹ ẹ to si n...
Gbajugbaja olorin lorilẹede Naijira, Adekunle Kosoko ti gbogbo eeyan mọ si Adekunle Gold lo ti jade wa sọ pe...
Minisita fun oun Amuṣagbara lorilẹede Naijira ti Aarẹ ṣẹṣẹ yan Joseph Tegbe ti kọ awọn ọrọ to n lọ...