Ijọba Ipinlẹ Ọyọ Da Ile Awọn Ajinigbe Wo Ni’badan
Ijọba ipinlẹ Ọyọ ti da ile olojule mẹta to wa l’agbegbe Lako l’ọna Aiyegun–Anaye nilu Ibadan eyi to niṣe...
Ijọba ipinlẹ Ọyọ ti da ile olojule mẹta to wa l’agbegbe Lako l’ọna Aiyegun–Anaye nilu Ibadan eyi to niṣe...
Gomina ipinlẹ Borno, Babagana Zulum ti ṣe sadankata fun awọn ọmọ ologun ilẹ wa paapaa julọ ikọ Operation HADIN...
Ile-ẹjọ giga to fikalẹ s’ilu Eko ti kede pe owo aadọfa biliọnu (₦110 billion) to n fa ariyanjiyan ti...
Agbarijọpọ awọn musulumi nipinlẹ Ọyọ ti bu ẹnu atẹ lu ofin to niṣe pẹlu Sharia eyi ti wọn ni...
Alema t’ilu Warri, Agba Oye Emmanuel Oritsejolomi Uduaghan ti sọ pe ki aya aarẹ orilẹede Naijiria, Remi Tinubu f’oju...
Gomina ipinlẹ Ọyọ, Onimọ ẹrọ Seyi Makinde ti buwọlu aṣẹ ẹlẹẹkeji ti ọdun 2026 lati ṣe ironilagbara fun eto...
Agbefọnranjade l’ori ayelujara Habeeb Hamzat ti ọpọ eeyan mọ si Peller lo ti f’oruka s’ọwọ ọrẹbinrin ati agbefọnranjade l’ori...
Gbajumọ ajijangbara ilẹ Yoruba, Sunday Adeyemo ti gbogbo eeyan mọ si Sunday Igboho ti leri pe oun ma fi...
Ile-iṣẹ ọlọpa ẹka tipinlẹ Ọṣun ti bẹrẹ iwadi l’ori igbiyanju ati ṣeku pa alaga ẹgbẹ oṣelu Accord nijọba ibilẹ...
Ilumọọka onkọrin fuji Remi Aluko ti sọrọ lori aisan to n ba ja leyi to ti fa ko ma...