Ẹgbẹ Awọn Olukọ Ẹka Tipinlẹ Ọyọ Ṣe Iwode Alalaafia Lati Fẹhonu Lori Awọn Ọmọ Ile-iwe Ati Awọn Olukọ Ti Wọn Jigbe Nijọba Ibilẹ Oriire Nipinlẹ Oyo
Ẹgbẹ awọn olukọ lorilẹede Naijira ẹka tipinlẹ Ọyọ ni wọn ti ṣe iwọde alalaafia lati fi aidunnu wọn han...

