Mo Ti Ba Ibalẹ Ọkan Ati Alaafia Pade Lẹyin Ọdun Meji Ti Igbeyawo Mi Ti Tuka – Frank Edoho
Ilumọọka sọrọ-sọrọ to jẹ atọkun eto “Who wants to be a millionaire” ti gbogbo eeyan nifẹsi lori ẹrọ amohunmaworan...
Ilumọọka sọrọ-sọrọ to jẹ atọkun eto “Who wants to be a millionaire” ti gbogbo eeyan nifẹsi lori ẹrọ amohunmaworan...
Lẹyin ti fọnran alawuyewuye kan jade sita, nibi ti olubori nigba kan ri ninu idije Ile Ẹlẹgbọn Agba (BB9ja...
Ẹsẹ ko gba ero ni gbọngan ayẹyẹ Eko Hotels l’aṣalẹ ana ti ayẹyẹ ami-ẹyẹ AMVCA ti waye nilu Eko....
Ilumọọka aṣoju awọn ile-iṣẹ to tun jẹ ọmọ gbajugbaja oṣere binrin Iyabo Ojo, Priscilla Ojo ti ṣaṣọ loju bii...
Seyi Vibez ati Adekunle Gold Awọn ọrọ buruku pau bi ibọn lo n bọọlẹ lati ẹnu gbajugbaja olorin takasufe...
Iro idunnu sọ lagboole gbajugbaja olorin Fuji nni, Wasiu Alabi ti gbogbo eeyan mọ si Pasuma bi ọmọ rẹ...
Ogbontarigi oṣere nni, Dele Odule ti awọn miiran mọ si “Baba Ijẹbu” lo ti tu aṣiri nla kan nipa...
Irawọ alawada, olorin ati amuludun ti ọpọ mọ si Nasboi lo ti fi ero rẹ han pe bi oun...
Ilumọọka oṣere, Funkẹ Akindele ti ọpọ mọ si Jenifa jẹ ko di mimọ pe oun kii lọ si ile-ijọsin...
Ẹsẹ o gb’ero ni’lu Ẹgba Alake lana ọjọ kejidinlọgbọn oṣu kẹta ọdun 2026 yii ni’bi ọdun Liṣabi ẹlẹkọkandinlogoji (39th)...