Blessing C.E.O R’ogun Ẹjọ, Wọn Lo Purọ Gb’owo Ni
Gbajumọ afọrọlede ati aṣoju awọn ile-iṣẹ lori ẹrọ ayelujara, Okoro Blessing Nkiruka ti gbogbo eeyan mọ si Blessing CEO...
Gbajumọ afọrọlede ati aṣoju awọn ile-iṣẹ lori ẹrọ ayelujara, Okoro Blessing Nkiruka ti gbogbo eeyan mọ si Blessing CEO...
Gbajugbaja olorin ẹmi ti orin rẹ ma n mu agbara dani – Esther Igbẹkẹle, lo ti pa’riwo si’ta pe...
Gbajumọ alufa ninu ẹsin Islam Sheikh Ahmad Gumi ti sọrọ lẹyin idakẹ ọjọ pipẹ lori abẹwo rẹ s’ilu Ibadan...
Lẹyin ọjọ kẹtalelogun l’akata awọn ajinigbe, Abilekọ Alamu to jẹ Olukọ Agba ọkan ninu awọn ile-ẹkọ ti ijinigbe kọlu...
Ijọba ipinlẹ Ọyọ ti da ile olojule mẹta to wa l’agbegbe Lako l’ọna Aiyegun–Anaye nilu Ibadan eyi to niṣe...
Ọọni ti Ile-ifẹ, kabiesi Enitan Babatunde Ogunwusi, Ọjaja Keji lo ti rọ awọn l’ade-l’ade ni ilẹ Yoruba lati lo...
Gomina ipinlẹ Borno, Babagana Zulum ti ṣe sadankata fun awọn ọmọ ologun ilẹ wa paapaa julọ ikọ Operation HADIN...
Ile-ẹjọ giga to fikalẹ s’ilu Eko ti kede pe owo aadọfa biliọnu (₦110 billion) to n fa ariyanjiyan ti...
Awọn ọmọ ibeji Olaide John-Paul to jẹ aburo minisita tẹlẹ fun ọrọ ina-ọba, Adebayọ Adelabu ni awọn ọlọpa ti...
Agbarijọpọ awọn musulumi nipinlẹ Ọyọ ti bu ẹnu atẹ lu ofin to niṣe pẹlu Sharia eyi ti wọn ni...