Ijinigbe Ọyọ: Ijọba Ẹ Ma Sun – Toyin Abraham, Kehinde Bankole, Ruth Kadiri, Jaywon Pariwo
Lẹyin iṣẹlẹ ijinigbe to waye si awọn akẹẹkọ ati olukọ ni ijọba ibilẹ Oriire ni agbegbe Ogbomoso ni ipinlẹ...
Lẹyin iṣẹlẹ ijinigbe to waye si awọn akẹẹkọ ati olukọ ni ijọba ibilẹ Oriire ni agbegbe Ogbomoso ni ipinlẹ...
Gbajugbaja oṣerebinrin Opeyemi Aiyeola ti ke pe awọn ilumọọka, awọn Lade Lade ati awọn ti wọn nifọn lẹẹkanna lawujọ...
Ọwọ ṣikun awọn ajọ to n risi ṣiṣe owo kumọkumọ lorilẹede Naijira (EFCC) ti tẹ Minisita fun oun amuṣagbara...
Gomina ipinlẹ Kano, Alhaji Abba Kabir Yusuf ti ọpọ mọ si Abba Gida Gida lo ti sọ oko ọrọ...
Gbajugbaja oṣerekunrin to ti ya sidi oṣelu bayi to n ṣ’oju ẹkun Surulere 1 nile igbimọ aṣofin t’ilu Eko,...
Sandra Edoho to jẹ iyawo tẹlẹ fun Frank Edoho, gbajugbaja sọrọsọrọ ti fi ẹsun kan-an pe niṣe lo maa...
Ile-ẹjọ giga nilu Abuja ti gba beeli gomina ipinlẹ Kaduna Nasir El-Rufai ni ọgọrun miliọnu lori ẹsun pe o...
Ilumọọka oṣerekunrin Emeka Ike ti fi erongba rẹ han lati dije dupo wọle aṣojuṣofin. Erongba yii lo fi lede...
Gbajugbaja arẹwa oṣerebinrin, Bukky Wright lo t’ẹnu bọ itan ti ọpọ awọn eniyan to fi mọ awọn ololufẹ rẹ...
Gbajugbaja oṣerebinrin to gb’ẹyẹ nibi ayẹyẹ AMVCA, Linda Ejiofor ti ṣalaye bi o ṣe ba ipenija pade nidi iṣẹ...