Ifẹnukonu Lo Ṣokunfa Ti Ẹni Ti Mo N Fẹ Tẹlẹ Ṣe Fimi Silẹ – Sandra Okunzuwa
Oṣerebinrin Sandra Okunzuwa ti sọrọ lori bi ọrẹkunrin rẹ tẹlẹri ṣe ja silẹ nitori oun fẹnukonu pẹlu oṣerekunrin ẹgbẹ...
Oṣerebinrin Sandra Okunzuwa ti sọrọ lori bi ọrẹkunrin rẹ tẹlẹri ṣe ja silẹ nitori oun fẹnukonu pẹlu oṣerekunrin ẹgbẹ...
Oṣere Tiata Lanre Adediwura ti jade wa sọrọ lori idi to ṣe kọ lati pada sidi sinima Wura to...
Ọọni ti Ile-ifẹ, Ọba Ẹnitan Adeyeye Ogunwusi y’ayọ awọn ibeji ọmọbakunrin tuntun jojolo ti Ọlọrun fi ta oun ati...
Lati nnkan ọjọ diẹ sẹyin ti iroyin jade pe gbajugbaja olorin olohun-arẹdodo, Chike ati Sandra to jẹ aya gbajumọ...
Abenugan tẹlẹri fun ile aṣoju-ṣofin orilẹ-ede Naijiria, Fẹmi Gbajabiamila to tun wa ni ipo Ajirọba iyẹn olori oṣiṣẹ lọọfisi...
Adije dupo aarẹ tẹlẹri labẹ asia ẹgbẹ oṣelu Labour Party (LP) Peter Obi ti sọ pe ọdun mẹrin gẹgẹ...
Gbajugbaja oṣere binrin nni, Foluke Daramola-Salako ti ya sidi oṣelu gẹgẹ bo ṣe ti gba fọọmu iferongba han labẹ...
Alakoso abi minisita tẹlẹ ri fun ọrọ ohun amusagbara ni orilẹ-ede Naijiria, Mamman Saleh ni ile-ẹjọ giga apapọ kan...
O ṣeeṣe ki gomina ipinlẹ Oyo, Onimọ ẹrọ Seyi Makinde fi erongba rẹ lede lati dije dupo aarẹ lorilẹede...
Olukọni tẹlẹri fun ikọ agba ọjẹ orilẹede Naijiria (Super Eagles), Sunday Oliseh ti sọ pe kikọ lati san owo...