Emeka Ike Jade Lati Ṣoju Ẹkun Bwari/AMAC Federal Constituency Nile Igbimọ Aṣojuṣofin Bẹẹ Lo N Rọ Awọn Ọmọ Orilẹede Naijiria Lati Gba Kaadi Idibo Wọn
Ilumọọka oṣerekunrin Emeka Ike ti fi erongba rẹ han lati dije dupo wọle aṣojuṣofin. Erongba yii lo fi lede...

