Mo Lero Pe Opin Ti De Ba Irin-ajo Mi Nidi Iṣẹ Tiata Ni Bi Ọdun Mẹta Sẹyin – Linda Ejiofor
Gbajugbaja oṣerebinrin to gb’ẹyẹ nibi ayẹyẹ AMVCA, Linda Ejiofor ti ṣalaye bi o ṣe ba ipenija pade nidi iṣẹ...
Gbajugbaja oṣerebinrin to gb’ẹyẹ nibi ayẹyẹ AMVCA, Linda Ejiofor ti ṣalaye bi o ṣe ba ipenija pade nidi iṣẹ...
Ile-iṣẹ ọlọpa ilẹ wa ti fi ọwọ osi juwe ile fun awọn ripẹtọ (Inspector) ọlọpa marun-un ni ipinlẹ Rivers...
Oṣerebinrin Sandra Okunzuwa ti sọrọ lori bi ọrẹkunrin rẹ tẹlẹri ṣe ja silẹ nitori oun fẹnukonu pẹlu oṣerekunrin ẹgbẹ...
Oṣere Tiata Lanre Adediwura ti jade wa sọrọ lori idi to ṣe kọ lati pada sidi sinima Wura to...
Ọọni ti Ile-ifẹ, Ọba Ẹnitan Adeyeye Ogunwusi y’ayọ awọn ibeji ọmọbakunrin tuntun jojolo ti Ọlọrun fi ta oun ati...
O ṣeeṣe ki gomina ipinlẹ Oyo, Onimọ ẹrọ Seyi Makinde fi erongba rẹ lede lati dije dupo aarẹ lorilẹede...
Olukọni tẹlẹri fun ikọ agba ọjẹ orilẹede Naijiria (Super Eagles), Sunday Oliseh ti sọ pe kikọ lati san owo...
Gomina tẹlẹri nipinlẹ Kano, Rabiu Musa Kwankwanso ti ṣaṣọ loju bi ọmọ rẹ obinrin ṣe gba niyanju ni ọdun...
Ilumọọka sọrọ-sọrọ to jẹ atọkun eto “Who wants to be a millionaire” ti gbogbo eeyan nifẹsi lori ẹrọ amohunmaworan...
Awọn alatilẹyin Igbakeji aarẹ tẹlẹri lorilẹede Naijira, Atiku Abubakar ti fi ikilọ ranṣẹ si awọn ẹgbẹ alatako gbogbo pe...